Ẹni ti óò ni ẹkọ àṣà Yorùbá dénú dénú lólè máa sọ pé láti mecca ni Yorùbá ti wá
Ifá tí àwọn bàbà ńlá wa ni, Ifá tí a mọ, Ifá Òpìtàn sọ pé Ifẹ̀ ni Orírun gbogbo ayé, ibi tí ojúmọ́ tí mọ́ wá
Àwọn Musulumi lati Mali àti Burkina Faso òní ló kọkọ gbé ọ̀rọ̀ mecca wá Àwọn Wangara àti Dendi pẹ̀lú Fulani Kìí ṣé ìtàn Yorùbá tòótọ́ o
Kò sí ẹnì kankan tó n jẹ Lamurudu ni Ilẹ̀ Yorùbá Àti pé, nígbà Oodua gàn, àwọn ìlú ńlá ńlá tí wà. Oodua kọ jẹ Ọba lórí àwọn ni Ifẹ̀. Láti Òkè-Ọ̀rà gangan ni Oodua ti wá, Oyè tí wọn dẹ ń jẹ ni Osin-ora
Ìtàn òṣì rè.
Ẹni ti óò ni ẹkọ àṣà Yorùbá dénú dénú lólè máa sọ pé láti mecca ni Yorùbá ti wá
Ifá tí àwọn bàbà ńlá wa ni, Ifá tí a mọ, Ifá Òpìtàn sọ pé Ifẹ̀ ni Orírun gbogbo ayé, ibi tí ojúmọ́ tí mọ́ wá
Àwọn Musulumi lati Mali àti Burkina Faso òní ló kọkọ gbé ọ̀rọ̀ mecca wá
Àwọn Wangara àti Dendi pẹ̀lú Fulani
Kìí ṣé ìtàn Yorùbá tòótọ́ o
Kò sí ẹnì kankan tó n jẹ Lamurudu ni Ilẹ̀ Yorùbá
Àti pé, nígbà Oodua gàn, àwọn ìlú ńlá ńlá tí wà. Oodua kọ jẹ Ọba lórí àwọn ni Ifẹ̀. Láti Òkè-Ọ̀rà gangan ni Oodua ti wá, Oyè tí wọn dẹ ń jẹ ni Osin-ora