
Àwọn ẹ̀dá tó ń gbé inú sánmàn àti àwọn awẹ́ ojú-òfuurufú
Science in Yoruba
0SubscribersÀwọn ẹ̀dá tó ń gbé inú sánmàn àti àwọn awẹ́ ojú-òfuurufú
Àwọn ẹ̀dá tó ń gbé inú sánmàn àti àwọn awẹ́ ojú-òfuurufú (Creatures living in the sky and layers of the atmosphere)
source
Reviews
0 %
User Score
0 ratingsRate This
Sharing
45 Related Posts
Related Posts
Modular kitchen furniture#aluminium #furniture
0 reactions
1 views Cooking African Traditional Food for Lunch / African village life #cooking #food
0 reactions
2 views Inside the Hadzabe Tribe Monkeys, Multiple Wives & Hunter-Gatherer Life
0 reactions
6 views Marie Antoinette – The Downfall & Death of a Queen Documentary
0 reactions
33 views [AP World History] Egyptian Society/Bantu Migrations/S India: Harappan
0 reactions
3 views
Yoruba science you're true the inventor of Yoruba geography ❤
Ẹ ṣe púpọ̀ 🎉❤
Inu mi dun si idanileko yii. More wisdom
Eni ti o se akoso gbalaja ofurufu ni a n pe ni Adeda, Aseda Eledumare, Olorun
Bravo grate research
E sounds pupo fun imole yi.
Eku ise opolo sir
Ibeere mi ni pe
Boba sepe obiiri alawe nibe ni osoonu (ozone) wa, se iyen ni pe eni to be rekoja awe Yi yoo ma fara kaasa awon ifewele (radiation) Orun?
Boba ribe awon onimo ijinle to n rekoja re n ko?
Eseun maama reti esi yin
E ku ise naa
Hmmm… omo oduduwa rere. Olorun a tunbo ma fi kun oye yin
Wooow well done sir
E Ku ise opolo, OLORUN OBA yoo ma fun yin ni imo si…..e jowo e maa ba wa gbinyanju lati ma so awon Nos. Wonyen ni Ede geesi, ki o le ma ye wa sii. E se pupo
God bless you.
OPOLO YIN O NI DARU ESE PUPO FUN IMO IJINLE TI EFIN YE WA ALLAH ONI JE KI OPOLOYIN DARU O!
Thanks for sharing
Great work! This is cool
God said it in Alquran that we made sky a protective shield for you
Thank u very much more wisdom and knowledge